MUSIC : Odun Ajayi - Ojo Ibi (Birthday) || @pastorodun



Odun Ajayi is a music minister. A praise and worship leader with dynasty, God as given him privilege to minister in so many places. By the grace of God he served as assistant worship leader at Daystar Christian Centre, Lagos, Nigeria. So many testimonies as been said by so many people on what God as done in their lives under his ministration (Odun Ajayi).

He released this single titled Ojo Ibi (Birthday) to appreciate God for his birthday this day. And dedicated it to the God of his life and to his biological son GILEAD DESIRE AJAYI. Which was born the same month.





LYRICS :


Mo dupe ore
Mo dupe ibi o

VERSE
L'ojo 'abini pataki ni ninu ojo 
Orisirisi lo sele lojo yen
L'agbegbe omo 
Igbe meji lo waiye 
Igbe ekun ati igbe ayo 
Eku ewu omo lo gbeyin 
Igbe t'omo ke waiye 
Iya la layo ju, l'ojo t'abi ni
Baba l'o lope to tobi ju 
P'o r'aiye omo
If you live to see your days
To celebrate
Boju re w'eyin ko wo 'ru re
Ni 'boji oku 

CHORUS (2×)
Ojo ibi 'ole jo ojo iku 
To r'ojo ayo ni o
T'aba fun o lati k'ojo ibi
Ko f'ogo f'Olu..

VERSE
L'ojo 'abi mi pataki ni 
Ninu ojo mi
Orisirisi lo sele lojo yen
L'ojo mo waiye
Igbe meji to waiye 
Ni'gbe ekun mi ati 
Igbe ayo awon eniyan
Eku ewu omo lo gbeyin 
Igbe ti mo ke waiye 
Iya mi la layo ju, 
l'ojo t'abi mi saiye
Baba mi l'o lope to tobi ju 
P'o r'aiye omo
If you live to see your days
You will celebrate
Boju re w'eyin ko wo 'ru re
Ni isa oku (Boya waa dupe).

CHORUS (2x)
Ojo ibi 'ole jo ojo iku 
To r'ojo ayo ni o
T'aba fun o lati k'ojo ibi
Ko f'ogo f'Olu..

VERSE
The little baby ojosi 
O ti d'okunrin o
I never knew I can see today 
Lati f'ogo f'Olu...
Oluwa mo dupe ore 
P'oo da mi si 
Ogbon ori 'ole s'akawe 
Ore re e mo dupe 
(Mo gbe'gba ope mi wa)

CHORUS (2x)
Ojo ibi 'ole jo ojo iku 
To r'ojo ayo ni o
T'aba fun o lati k'ojo ibi
Ko f'ogo f'Olu..

BRIDGE
Blow your candle
Make your wishes 
Comes true
God's mercies 
And grace I enjoyed 
(Repeat)

CHORUS (4×)
Ojo ibi 'ole jo ojo iku 
To r'ojo ayo ni o
T'aba fun o lati k'ojo ibi
Ko f'ogo f'Olu..



Connect:
Instagram: odun_ajayi
Twitter: 
@pastorodun
Facebook: Odun Ajayi

AkomolafeBlog

Award Winning Blogger, Social Media Optimizer/Strategist & Entrepreneur.

Post a Comment

DISCLAIMER: THE POSTS ON THIS BLOG ARE NOT THE BELIEF OF THE AUTHOR, THEY ARE JUST NEWS AND UPDATES TO KEEP U INFORMED!!!

Previous Post Next Post